Lunes, 27 Junio 2016 21:34

Omolú

CANTICAS DE OMOLU
 
1- A jí dàgòlóònòn kí wa sawo orò. Dàgò ilé ilé, dàgòlóònòn kí wa sawo orò
2- Ó àjerín l'ònòn lóòde bá ìwà ó bò-m-bàtà. Aé lóòde bá ìwà ó bò-m-bàtà
3- Onílè wà àwa lésè Òrìsà, opé ire. E kòlòbó e kòlòbó sín sín, sín sín. Sín Sín kòlòbó e kòlòbó
4- Omolú pè olóre a àwúre e kú àbò
5- Omolú sóbóló ojú wa ó nòn wa le jé ni fojúrí
6- Omolú pè a júbà a èkó, oníyè. Omolú aráayé pè a júbà a èko. Oníyè, Omolú pè a júbà a èkó oníyè
7- Àáròo rè gbèlé gbèlé (gbèlè) mi báa yí lówó. E njí Omolú tó gbèlé gbélé (gbèlé) mi báa yí lówó. Ó jé ji àwúre
8- Omolú tó ló kun eron ènìòn e ló e ló e kun
9- Oníyè tó gígbón mi jé a npenpe e ló. Gbè wàiyé tó ní gbón mi, jé npepe. Omolú wàiyé (Obalúwàié) tó ní gbón mi
10- Ó ìjeníìyà bàbá a sìn e gbogbo wa lé. Ó ìjeníìyà bàbá a sìn e gbogbo wa lé ó
11- A jí nsùn aráayé ó ló ìjeníìyà e wa ká lo. Sápadà aráayé ló ìjeníìyà e wa ká lo ìjeníìyà. Aráayé, é ajeniníìyá, ajeniníìyá, àgó ajeniníìyá. Máàa ká lo ajeniníìyá
12- Ó Táálá bé okùnrin wa ki lo kun, Táálá bé okùnrin. Abénilórí ìbé rí ó ní je oluwàiyé Táálá bé okùnrin. Ó ní a ló ìjeníìya ajàgun tó ló ìjeníìyà olúwáiyé. Táálá bé okùnrin
13- Ó gbélé iko sàlà rè sàlà rè lórí
14- Ó àfomó ó fá ojú rè mò fá, aráayé njó jó
15- Wúlò ní wúlò, a nilè gbèlé ìbé kò
16- Olórí pa, olórí ìjeníìyà a pàdé
17- A bàbá òrun mó fé, a bàbá òrun e njó jó
18- Ó kíní gbè fáárà faroti, ó kíní gbè fáárà. Àfaradà, oní pópó oníyè, kíní ìyìyà wa ìfaradà
19- Àgò jó ilé omo Omolú jó, àgò jó ilé. Omo Omolú jó àgò jó ilé
20- Elé fúló àiyé elé fúló a lè inón. Elé fúló a jí ns`n elé fúló Ajagùnnón
21- Aráayé a je nbo, olúgbàje a je nbo
22- Kóró nló awo, kóró nló awo, sé ó gbèje
23- Jó a lé ijó, é jó a lé ijó, é jó a lé ijó. Àfaradà a lé njó ó ngbèlé
24- Kíní a awo ó ní kójó, jé ó ngbélè. Ki wa jó e ki wa jó ó ní kójó, jí ngbélè ki wa jó
25- Àká ki fàbò wíwà. Wáá kalé, wáa kalé sé awo orò
26- Sá-sá wa òrò fún awo, sá-sá wa òrò
Publicado en ORIXAS
Jueves, 23 Junio 2016 16:52

ORIXAS

 
Publicado en Axegeneral

AXE DE POMBA GIRA © 2016 Política de privacidad Términos y condiciones