Lunes, 27 Junio 2016 21:42

Naná

 

CANTICAS DE NANÁ

 

1- Eni koríko odò ki wàlè, omon nílè kò ràjò. Nàná ikú rè omon nílè kò ràjò, kò ràjò, kò rajò, ó félé lé , kò ràjò
2- Òdì Nàná ní ewà, léwà léwà e
3- E Nàná olúwàiye e pa e pa
4- E taláàyà àjò olúwodò ki wa àjò
5- A bímon máà kú máa káwó òde kò ríbo dé
6- Àwa ló bimon ayò Olóko, Nàná ayò
7- Nàná ìyá kò lódò, Nàná e Òrìsà. Nàná e Nàná a ayò, Nàná ìyà kò lódò
8- Òdì Nàná ayò ó ibi rìn sá-sá ó lóòde. Ó ibin rìn sá-sá, òdì Nàná ayò, Nàná ayò olùwodò sésé
9- Ó ibi rìn odàra tó sé a àárè Nàná olúwodò. Ibi rìn odára tó se àárè olúwa sè yìn sè yìn
10- Ibi rìn odàra tó sé àwa àárè kò mò rè dìde. Ibi rìn odàra tó sé àwa àárè kò mò rè Nàná olúwàiyé
11- Ó ìyá wa òré ó ní ayalóòde, ó ìyá wa òré. Ó ní ayalóòde
12- Ni odun kéèta ti bàbá rè ikú ó ni òun náà na ló. Tèdó níinú igbó ó ní sè ará rè sé ìyálóòde ilú yìí
13- E tí mòn sòn fún omoode, e tí mòn jé ó
14- Ó ìyá àbíkú ó, àbíkú olóyíyè
Publicado en ORIXAS
Jueves, 23 Junio 2016 16:52

ORIXAS

 
Publicado en Axegeneral

AXE DE POMBA GIRA © 2016 Política de privacidad Términos y condiciones