Exú Orixá

 
CANTICAS DE EXÚ ORIXÁ
 
1- A pàdé Olóònòn e mo júbà Òjìsé. Àwa sé awo
2- Elégbára réwà a sé awo. Bara Olóònòn àwa fún àgò
3- A jí kí ire ni Èsù, Èsù kà bí kà bí
4- Elégbára Èsù ó sá kéré kéré. Ekesan Bará Èsù ó sá kéré kéré
5- E Elégbára Elégbára Èsù Aláyé
6- Ó wà lésè l'abowolé s'orí agbékó ìlèkùn
7- Èsù wa jú wò mòn mòn ki wó Odára. Laróyé Èsù wa jú wò mòn mòn ki wò Odára. Èsù awo
8- Odára ló sòro, Odára ló sòro lóònòn. Odára ló sòro e ló sòro Odára ló sóro lóònòn
9- Òjísé pa lé fún awo, Odára pa lé sóba
10- Elégbára léwà légbára Èsù a jú wò mòn mòn ki a awo
11- Kò mo nrí ìjà rè ó ìjà rè ó Èsù Olóònòn
12- Ó jí gbálè à kàrà ó, Èsù sóròkè
13- A jí kí Barabo e mo júbà, àwa kò sé. A jí kí Barabo e mo júbà, e omodé ko èkó ki. Barabo e mo júbà Elégbára Èsù l'ònòn
14- Bará ó bebe Tirirí l'ònòn. Èsù Tirirí
15- Gókè gókè Odára, Odára bàbá ebo. Gókè gókè nidánón
16- Inón inón mo júbà e e mo júbà. Àgò mo júbà
17- E má won léébá nón, Kò rí ìjà. E má jékí kò rí ìjà
18- Olóònòn àwa Bará Kétu
19- Èsù so sóròkè. Elégbára ki a awo. Elégbára légbáa ó
20- Kétu ké Kétu e Èsù Alákétu. Elégbára Kétu
21- Yemonja kó nta ródò, Èsù a inón kò
22- Àgòlóònòn àwa pè nbo, àgòlóònòn e
23- Àgò nbo nbo Laróyè
24- Sónsó òbe. Odára kò l'orí erù, Laróyè. Odára kò l'orí ebo
25- Alákétu rè Kétu Bará. Èsú máa ló

AXE DE POMBA GIRA © 2016 Política de privacidad Términos y condiciones